Kronika Keji 29:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn ohun èlò tí Ahasi ọba ti patì nígbà tí ó ṣe aiṣododo ni a ti tọ́jú, tí a sì ti yà sí mímọ́. A ti kó gbogbo wọn siwaju pẹpẹ OLUWA.”

Kronika Keji 29

Kronika Keji 29:10-26