Kronika Keji 26:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Usaya tún kọ́ àwọn ilé ìṣọ́ ní Jerusalẹmu níbi Ẹnubodè tí ó wà ní igun odi, ati sí ibi Ẹnubodè àfonífojì, ati níbi Ìṣẹ́po Odi. Ó sì mọ odi sí wọn.

Kronika Keji 26

Kronika Keji 26:7-17