Kronika Keji 26:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará Amoni ń san ìṣákọ́lẹ̀ fún Usaya, òkìkí rẹ̀ kàn káàkiri títí dé agbègbè ilẹ̀ Ijipti, nítorí pé ó di alágbára gan-an.

Kronika Keji 26

Kronika Keji 26:5-12