Kronika Keji 22:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìwà burúkú ni òun náà ń hù bíi ti Ahabu, nítorí pé ìyá rẹ̀ ní ń darí rẹ̀ sí ọ̀nà ibi.

Kronika Keji 22

Kronika Keji 22:1-11