Kronika Keji 22:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ahasaya jẹ́ ẹni ọdún mejilelogoji, nígbà tí ó jọba; ó sì wà lórí oyè fún ọdún kan ní Jerusalẹmu. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Atalaya, ọmọ ọmọ Omiri.

Kronika Keji 22

Kronika Keji 22:1-6