Kronika Keji 21:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Sibẹsibẹ OLUWA kò pa ìdílé Dafidi run nítorí majẹmu tí ó ti bá Dafidi dá, ati ìlérí tí ó ti ṣe pé ọmọ rẹ̀ ni yóo máa wà lórí oyè títí lae.

Kronika Keji 21

Kronika Keji 21:1-8