Kronika Keji 21:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó tẹ̀ sí ọ̀nà burúkú tí àwọn ọba Israẹli rìn, ó ṣe bí ìdílé Ahabu ti ṣe, nítorí pé ọmọ Ahabu ni iyawo rẹ̀. Ó ṣe ohun tí ó burú lójú OLUWA.

Kronika Keji 21

Kronika Keji 21:3-14