Kronika Keji 21:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Jehoramu ní arakunrin mẹfa, tí wọ́n jọ jẹ́ ọmọ Jehoṣafati, orúkọ wọn ni, Asaraya, Jehieli, ati Sakaraya, Asaraya, Mikaeli ati Ṣefataya.

Kronika Keji 21

Kronika Keji 21:1-5