Kronika Keji 21:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Jehoṣafati kú, wọ́n sin ín pẹlu àwọn baba rẹ̀ ninu ibojì àwọn ọba ní ìlú Dafidi. Jehoramu, ọmọ rẹ̀ sì jọba lẹ́yìn rẹ̀.

Kronika Keji 21

Kronika Keji 21:1-2