Kronika Keji 20:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo nǹkan yòókù tí Jehoṣafati ṣe láti ìbẹ̀rẹ̀ dé òpin, ni a kọ sinu ìwé ìtàn Jehu ọmọ Hanani, tí ó jẹ́ apá kan ìtàn àwọn ọba Israẹli.

Kronika Keji 20

Kronika Keji 20:28-37