Kronika Keji 20:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn kò pa àwọn pẹpẹ ìrúbọ run; àwọn eniyan kò tíì máa fi tọkàntọkàn sin Ọlọrun àwọn baba ńlá wọn.

Kronika Keji 20

Kronika Keji 20:30-34