Kronika Keji 20:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Jehoṣafati dojúbolẹ̀, gbogbo àwọn ará Juda ati àwọn ará Jerusalẹmu náà bá dojúbolẹ̀, wọ́n sì sin OLUWA.

Kronika Keji 20

Kronika Keji 20:9-27