Kronika Keji 18:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni Sedekaya, ọmọ Kenaana súnmọ́ Mikaya, ó gbá a létí, ó wí pé, “Nígbà wo ni ẹ̀mí OLUWA fi mí sílẹ̀ tí ó wá ń bá ọ sọ̀rọ̀?”

Kronika Keji 18

Kronika Keji 18:15-32