Kronika Keji 18:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Mikaya ní, “OLUWA ni ó mú kí àwọn wolii rẹ wọnyi máa sọ àsọtẹ́lẹ̀ èké, ṣugbọn àjálù burúkú ni OLUWA ti pinnu pé yóo dé bá ọ.”

Kronika Keji 18

Kronika Keji 18:12-26