Kronika Keji 14:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó kó gbogbo àwọn pẹpẹ ìrúbọ ati àwọn pẹpẹ tí wọ́n ti ń sun turari ní gbogbo àwọn ìlú Juda jáde. Alaafia sì wà ní àkókò ìjọba rẹ̀.

Kronika Keji 14

Kronika Keji 14:1-13