Kronika Keji 14:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó pàṣẹ fún àwọn ọmọ Juda láti wá ojurere OLUWA Ọlọrun àwọn baba wọn ati láti pa òfin rẹ̀ mọ́.

Kronika Keji 14

Kronika Keji 14:1-12