Kronika Keji 13:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Abija kó ogún ọ̀kẹ́ (400,000) akọni ọmọ ogun jọ láti bá Jeroboamu jagun. Jeroboamu náà kó ogoji ọ̀kẹ́ (800,000) akọni ọmọ ogun jọ.

Kronika Keji 13

Kronika Keji 13:1-12