Kronika Keji 13:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sì wà lórí oyè ní Jerusalẹmu fún ọdún mẹta. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Mikaya, ọmọ Urieli ará Gibea.Nígbà kan, ogun bẹ́ sílẹ̀ láàrin Abija ati Jeroboamu.

Kronika Keji 13

Kronika Keji 13:1-12