Kronika Keji 13:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Jeroboamu kò sì lè gbérí ní àkókò Abija. Nígbà tí ó yá Ọlọrun lu Jeroboamu pa.

Kronika Keji 13

Kronika Keji 13:16-22