Kronika Keji 13:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Abija lé Jeroboamu, ó sì gba ìlú Bẹtẹli, ati Jeṣana, ati Efuroni ati àwọn ìletò tí ó yí wọn ká lọ́wọ́ rẹ̀.

Kronika Keji 13

Kronika Keji 13:18-22