Kronika Keji 11:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn alufaa ati àwọn ọmọ Lefi tí wọ́n wà ní gbogbo ilẹ̀ Israẹli sì fara mọ́ Rehoboamu. Gbogbo wọn bẹ̀rẹ̀ sí wọ́ lọ sọ́dọ̀ rẹ̀.

Kronika Keji 11

Kronika Keji 11:5-21