Kọrinti Kinni 7:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí wọn kò bá lè mú ara dúró, wọ́n níláti gbeyawo. Nítorí ó sàn kí wọ́n gbeyawo jù pé kí ara wọn máa gbóná nítorí èrò ìbálòpọ̀ ọkunrin ati obinrin.

Kọrinti Kinni 7

Kọrinti Kinni 7:7-12