Kọrinti Kinni 7:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo ní ọ̀rọ̀ fún àwọn tí ó ti gbeyawo: ọ̀rọ̀ tèmi fúnra mi kọ́, bíkòṣe ti Oluwa wa. Aya kò gbọdọ̀ kọ ọkọ rẹ̀.

Kọrinti Kinni 7

Kọrinti Kinni 7:1-11