Kọrinti Kinni 7:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹrú ni ọ́ nígbà tí a fi pè ọ́? Má ṣe gbé e lékàn. Ṣugbọn bí o bá ní anfaani láti di òmìnira, lo anfaani rẹ.

Kọrinti Kinni 7

Kọrinti Kinni 7:16-28