Kọrinti Kinni 4:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí mo rò pé Ọlọrun ti fi àwa òjíṣẹ́ hàn ní ìkẹyìn bí àwọn tí a dá lẹ́bi ikú, nítorí a ti di ẹni tí gbogbo ayé fi ń ṣe ìran wò: ati àwọn angẹli, ati àwọn eniyan.

Kọrinti Kinni 4

Kọrinti Kinni 4:1-15