Kọrinti Kinni 4:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwa di òmùgọ̀ nítorí ti Kristi, ẹ̀yin wá jẹ́ ọlọ́gbọ́n ninu Kristi! Àwa jẹ́ aláìlera, ẹ̀yin jẹ́ alágbára! Ẹ̀yin jẹ́ ọlọ́lá, àwa jẹ́ aláìlọ́lá!

Kọrinti Kinni 4

Kọrinti Kinni 4:4-17