Kọrinti Kinni 3:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí alábàáṣiṣẹ́pọ̀ ni wá lọ́dọ̀ Ọlọrun. Ẹ̀yin ni ọgbà Ọlọrun.Tẹmpili Ọlọrun sì ni yín.

Kọrinti Kinni 3

Kọrinti Kinni 3:1-15