Kọrinti Kinni 3:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀kan ni ẹni tí ó ń gbin irúgbìn ati ẹni tí ó ń bomi rin ín. Nígbà tí ó bá yá, ẹnìkọ̀ọ̀kan wọn yóo gba èrè tirẹ̀ gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ rẹ̀ bá ti rí.

Kọrinti Kinni 3

Kọrinti Kinni 3:3-15