Kọrinti Kinni 3:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ta ni Apolo? Ta ni Paulu? Ṣebí iranṣẹ ni wọ́n, tí ẹ ti ipasẹ̀ wọn di onigbagbọ? Olukuluku wọn jẹ́ iṣẹ́ tirẹ̀ bí Ọlọrun ti rán an.

Kọrinti Kinni 3

Kọrinti Kinni 3:4-13