Kọrinti Kinni 3:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí nígbà tí ẹnìkan ń sọ pé ẹ̀yìn Paulu ni òun wà, tí ẹlòmíràn ń sọ pé ẹ̀yìn Apolo ni òun wà ní tòun, ó fihàn pé bí eniyan kan lásán ni ẹ̀ ń hùwà.

Kọrinti Kinni 3

Kọrinti Kinni 3:1-13