Kọrinti Kinni 2:15-16 BIBELI MIMỌ (BM)

15. Ẹni tí ó bá ní Ẹ̀mí lè wádìí ohun gbogbo, ṣugbọn eniyan kan lásán kò lè wádìí òun alára.

16. Nítorí ó wà ní àkọsílẹ̀ pé,“Ta ni ó mọ inú Oluwa?Ta ni yóo kọ́ Oluwa lẹ́kọ̀ọ́?”Ṣugbọn irú ẹ̀mí tí Kristi ní ni àwa náà ní.

Kọrinti Kinni 2