Kọrinti Kinni 3:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin ará, n kò lè ba yín sọ̀rọ̀ bí ẹni ti Ẹ̀mí, bíkòṣe bí ẹlẹ́ran-ara, àní gẹ́gẹ́ bí ọmọ-ọwọ́ ninu Kristi.

Kọrinti Kinni 3

Kọrinti Kinni 3:1-4