Kọrinti Kinni 15:49 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí a ti gbé àwòrán ti ẹni erùpẹ̀ wọ̀, bẹ́ẹ̀ gan-an ni a óo gbé àwòrán ti ẹni ọ̀run wọ̀.

Kọrinti Kinni 15

Kọrinti Kinni 15:47-57