Kọrinti Kinni 15:48 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹni tí a fi erùpẹ̀ dá ti rí, bẹ́ẹ̀ ni gbogbo àwọn tí a fi erùpẹ̀ dá rí. Bí ẹni tí ó wá láti ọ̀run ti rí, bẹ́ẹ̀ ni gbogbo àwọn ti ọ̀run rí.

Kọrinti Kinni 15

Kọrinti Kinni 15:45-53