Kọrinti Kinni 15:45 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó wà ninu àkọsílẹ̀ pé, “Adamu, ọkunrin àkọ́kọ́ di alààyè;” ṣugbọn Adamu ìkẹyìn jẹ́ ẹ̀mí tí ó ń sọ eniyan di alààyè.

Kọrinti Kinni 15

Kọrinti Kinni 15:39-53