Kọrinti Kinni 15:44 BIBELI MIMỌ (BM)

A gbìn ín pẹlu ara ti ẹ̀dá, a jí i dìde ní ara ti ẹ̀mí. Bí ara ti ẹ̀dá ti wà, bẹ́ẹ̀ ni ti ẹ̀mí wà.

Kọrinti Kinni 15

Kọrinti Kinni 15:36-48