Kọrinti Kinni 15:39 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ẹran-ara kì í ṣe oríṣìí kan náà. Ọ̀tọ̀ ni ẹran-ara eniyan, ọ̀tọ̀ ni ti ẹranko, ọ̀tọ̀ ni ti ẹyẹ, ọ̀tọ̀ ni ti ẹja.

Kọrinti Kinni 15

Kọrinti Kinni 15:34-40