Kọrinti Kinni 15:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun ni ó ń fún un ní ara tí ó bá fẹ́, a fún irúgbìn kọ̀ọ̀kan ní ara tirẹ̀.

Kọrinti Kinni 15

Kọrinti Kinni 15:35-39