Kọrinti Kinni 15:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ẹnìkan lè bèèrè pé, “Báwo ni a óo ti ṣe jí àwọn òkú dìde? Irú ara wo ni wọn óo ní?”

Kọrinti Kinni 15

Kọrinti Kinni 15:28-39