Kọrinti Kinni 15:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ ronú, kí ẹ sì máa ṣe dáradára. Ẹ má dẹ́ṣẹ̀ mọ́. Àwọn tí kò mọ Ọlọrun wà láàrin yín! Mò ń sọ èyí kí ojú kí ó lè tì yín ni.

Kọrinti Kinni 15

Kọrinti Kinni 15:30-37