Kọrinti Kinni 14:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí nǹkankan bá wà tí wọ́n fẹ́ mọ̀, kí wọ́n bi àwọn ọkọ wọn ní ilé. Ìtìjú ni fún obinrin láti sọ̀rọ̀ ninu ìjọ.

Kọrinti Kinni 14

Kọrinti Kinni 14:26-40