Kọrinti Kinni 14:34 BIBELI MIMỌ (BM)

àwọn obinrin gbọdọ̀ panumọ́ ninu ìjọ. A kò gbà wọ́n láyè láti sọ̀rọ̀. Wọ́n níláti wà ní ipò ìtẹríba, gẹ́gẹ́ bí Òfin ti wí.

Kọrinti Kinni 14

Kọrinti Kinni 14:32-40