Kọrinti Kinni 14:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tí ó ní ẹ̀bùn ìsọtẹ́lẹ̀ níláti lè káwọ́ ara wọn nígbà tí ẹ̀mí bá gbé wọn láti sọ àsọtẹ́lẹ̀.

Kọrinti Kinni 14

Kọrinti Kinni 14:31-40