Kọrinti Kinni 14:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo yín lè sọ àsọtẹ́lẹ̀, lọ́kọ̀ọ̀kan, kí gbogbo yín lè rí ẹ̀kọ́ kọ́, kí gbogbo yín lè ní ìwúrí.

Kọrinti Kinni 14

Kọrinti Kinni 14:22-32