Kọrinti Kinni 13:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìfẹ́ kò lópin. Ní ti ọ̀rọ̀ wolii, wọn yóo di ohun tí kò wúlò mọ́. Ní ti àwọn èdè àjèjì wọn yóo di ohun tí a kò gbúròó mọ́. Ní ti ìmọ̀, yóo di ohun tí kò wúlò mọ́.

Kọrinti Kinni 13

Kọrinti Kinni 13:1-9