Kọrinti Kinni 13:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìfẹ́ a máa fara da ohun gbogbo, a máa gba ohun gbogbo gbọ́, a máa ní ìrètí ninu ohun gbogbo, a sì máa foríti ohun gbogbo.

Kọrinti Kinni 13

Kọrinti Kinni 13:1-9