Kọrinti Kinni 11:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ pé Kristi ni orí fún olukuluku ọkunrin, ọkunrin ni orí fún obinrin, Ọlọrun wá ni orí Kristi.

Kọrinti Kinni 11

Kọrinti Kinni 11:1-13