Kọrinti Kinni 11:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo yìn yín nítorí pé ẹ̀ ń ranti mi nígbà gbogbo, ati pé ẹ kò jẹ́ kí àwọn ẹ̀kọ́ tí mo fi kọ yín látijọ́ bọ́ lọ́wọ́ yín.

Kọrinti Kinni 11

Kọrinti Kinni 11:1-11