Kọrinti Kinni 11:24 BIBELI MIMỌ (BM)

lẹ́yìn tí ó ti dúpẹ́ tán, ó bù ú, ó ní, “Èyí ni ara mi tí ó wà fun yín. Ẹ máa ṣe èyí ní ìrántí mi.”

Kọrinti Kinni 11

Kọrinti Kinni 11:18-27