Kọrinti Kinni 11:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí láti ọ̀dọ̀ Oluwa ni mo ti gba ohun tí mo fi kọ yín, pé ní alẹ́ ọjọ́ tí a fi Jesu Oluwa lé àwọn ọ̀tá lọ́wọ́, ó mú burẹdi,

Kọrinti Kinni 11

Kọrinti Kinni 11:22-32